ìlú, ìlú nlá, ìlúàwọn ara ìlú
town, city - la ville

Yoruba English français
ìletòabúlé le village
ìgboro, àárín ìgboro downtown le centre-ville
gbàngàn ìdájọgbàngàn ìlúìtẹ ìjọba,
gbàngbà ìdájọ ìlúilé ìpàdé àkóso ìlú
town/city hall la mairie
onídàjọ ìlúolórí ìlú mayor le maire
ọnà híhá, ọnà tóóró alley la ruelle
ọnà ìgboro ìlúìtaòpópó street la rue
ọnà gbòòrò,
ojú ọnà àyè
l'avenue
àárín ọjà public square la place (publique)
mọṣálásí mosque la mosquée
ilé ìjọsìn
ilé ọlọrunìjọ onígbàgbọ
church l'église
ilé ìsìn àwọn Júù la synagogue
ilé ìsìn ọlọrun
tàbí òrìṣà
le temple
ààfinilé ìṣọ castle
fortress
le château
la forteresse
ilé ìṣọ gígailé ẹṣọ tower la tour
ààfin, ilé ọba palace le palais
ilé èrò tí
a nrí onjẹ rà
hotel l'hôtel
ilé onjẹ àrójẹ le restaurant
alásèase-onjẹ cook, "chef" le cuisinier
adúró tini, agbawó onjẹ, adìgbàró waiter
waitress
le serveur
la serveuse
ilé ọtí títàilé ọtí coffee-house
tea-house
le café, le bar
le salon de thé
ilé ìwé àjọ
ìkọọwéilé ẹkọ
school l'école
olórí, alákoso, ọgá schoolmaster le maître d'école
ọmọwé, ọlọgbọn, akékọọ schoolboy, scholar
schoolgirl
l'écolier
l'écolière
olùkọ, olùkọni, akọnilẹkọọ teacher, professor le professeur
akòwéọkàwé,
ọmọ ilé ìwé, ọmọ-iṣẹ, akẹkọọ
student, (pupil) l'étudiant
university l'université
akọwé ìròhìn
ìwè ìròhìn
journalist
newspaper
le journaliste
le journal
ìwé book le livre
ìwé àṣàjọ ọrọ,
ìwé ìtúmọ ọrọ, àtúmọ-èdè
dictionary le dictionnaire
ilé ìkàwé, ìkójọpọ ìwé library la bibliothèque
olútòju ilé ìkàwé librarian le bibliothécaire
ilé-ọjà ìwé bookshop, bookstore
bookseller
la librairie
le libraire
ilé-ọjàa shop, store la boutique, le magasin
ọjà
ọjà ñlá
market
supermarket
le marché
le supermarché
oníṣòwòọlọjà merchant le marchand
ilé ìse àkàrà,
ilé alákàrà, ilé àsè
bakery la boulangerie
alásè,
adínkàrà, adín-ýkan
baker le boulanger
afárunonígbàjámọ, onídìríonígbàjámọ hairdresser le coiffeur
gbọngàn-erétíátàilé àkójọpọ
láti wo ẹrẹ
theater le théâtre
àwòrán tí nrìnilé
àwòrán tí nrìn
cinema le cinéma
iré àwòrán
tí nrìn/tí fohùnfíìmù
movie le film
òṣeré
òṣeré, eléré
actor
actress
l'acteur
l'actrice
iré orinìfìmọṣọkan le concert
akọrinolórinonírárà singer le chanteur
olórin afunfèrè aludùrù,
akọrin
musician le musicien
ilé àkójọpọ ohun ìgbanì,
ilé ìṣura
museum le musée
alábójútó, olórí,
alákoso, afọnàhàn
manager, director le directeur
akọwé secretary la secrétaire
ilé ìpamọ owó bank la banque
ọgá ilé ìfi
owó pamọ sí
banker le banquier
banknote, bill le billet
credit card la carte de crédit
iwe ìgbowó ní bánkì cheque, (check) le chèque
owó money l'argent
pàrọ owóìpàrọ change la monnaie
brothel le bordel
pañṣágà obìnrin,
ọdọkọ, àgbèrè, kárúwà,
àgbèrèaṣẹwóọdọkọ
prostitute la prostituée
olè ajínilóhun
jàgùdà ìgárá
thief, robber le voleur
ọlọpàá policeman le policier
àwọn ọlọpàá la police
ilé iṣẹ àwọn ọlọpàá police station le commissariat
ilé ẹwọn, ilé túbú prison, jail la prison
ẹlẹwọn, ará túbú, oþdè prisoner le prisonnier
ìtẹ òkú,
ìtẹ òkúibi ìsìnkúìtẹ
graveyard, cemetery le cimetière
ibojì, ìbòjiibi ìsínkúsàre,
isà òkú
grave, tomb la tombe
òkúta orí ìbòji,
òkúta ìsàmì ìbòji
gravestone la pierre tombale