le transport

Yòrùbá English français
ìrìn àjò (kúkúrú)
alárìnkiri, arìnnà àjò
travel, trip
traveler
le voyage
le voyageur
ẹ́ru luggage, baggage les bagages
àpótí suitcase la valise
owó bodè Customs la Douane
ìwé ìwọ̀lú míràn, físà le visa
ìwé ìyọdà ìwọlú
tàbí ìjádelọ
passport le passeport
pápá bàlúù,
pápá ọkọ̀ òfúrufú
airport l'aéroport
bàlúù ọkọ̀ òfúrufú airplane, aeroplane l'avion
helicopter l'hélicoptère
atukọ̀ bàlúù,
afọnàhàn nínú ọkọ̀
pilot le pilote
ìránṣẹ́, olùtọ́jú ilé le steward
èbúté, ibi ìgúnlẹ̀ sí le port
ilé oníná àfewu
han atúkọ
lighthouse le phare
ọkọ̀ ship le navire
ọkọ̀-ìgbájá, ọkọ̀ kékeré boat le bateau
ọkọ̀ ojú irin, rélùwe le train
ìdí ọkọ̀ train station la gare
àmì ìwé ìgbàwọlé ticket le titre de transport
ilọ, àtilọ,
iku, kurò
departure le départ
dídé, atidé,
àbọ, bíbọ̀
arrival l'arrivée
ọ̀nà road la route
ọ̀nà gbàngbà,
òpópó ọ̀nà
highway, motorway l'autoroute
awakọ̀
ìwé ìwakọ̀
driver
driving license
le chauffeur, le conducteur
le permis de conduire
ọkọ̀ akérò truck, lorry
van
le camion
la camionnette
ọkọ̀ akérò bus l'autobus, (l'autocar)
ìdádúró ìsé stop l'arrêt
ọkọ̀ ayọkẹlẹ agbèrò cab le taxi
ọkọ̀ aláfê travel trailer, caravan la caravane
ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ car la voiture, l'automobile
ìdá ọkọ̀ dúró
sí ojú kan
car park le "parking"
ilé ìpamọ́ ọkọ̀,
ilé àtúnse ọkọ̀
le garage
atẹ́rọṣe mechanic le mécanicien
epo (mọtò), epo ọkọ̀ gasoline, (petrol) l'essence
kẹ̀kẹ́ wheel la roue
atapùpù, alùpùpù,
kẹ̀kẹ́ ẹlẹsẹ mẹjì afepo rìn
motorcycle la moto, le vélomoteur
kẹ̀kẹ́ olóògéré bicycle, bike la bicyclette, le vélo
onírìnkiri pedestrian le piéton
ọnà olókúta, ọnà ọlọdà,
ọnà alámọ líle
pavement, sidewalk le trottoir