aago ìdánijí
alarm-clock
le réveil

àkókò - time - le temps

Yoruba English français
aago, agogo clock l'horloge
aago ọ̀wọ́ (wrist)watch la montre
wákàtí hour l'heure
ìṣẹ́jú la minute
ìṣẹ́jú àáyá second la seconde
òwúrọ̀, àrọ, ìdájí morning le matin, la matinée
ọ̀sán-gangan
agbede-méjì ọjọọjọkanrí
midday, noon midi
ọ̀sán, ọjọ́rọ̀, ìrọ̀lẹ́ afternoon l'après-midi
ọjọ́, ọ̀sán day le jour, la journée
ìrọ̀lẹ́, àṣalẹ́, ọjọ́rọ̀, alẹ́ evening le soir, la soirée
òru night la nuit
ọ̀gànjọ́, óru, àjin midnight minuit
àná, lánà yesterday hier
lóní, ọjọ́ òní today aujourd'hui
ọla, lọla tomorrow demain
ọsẹ kan, ọjọ́ méje week la semaine
ìparí ọsẹ weekend la fin de semaine
ìsimi díẹ lẹ́yìn iṣẹ́,
ọludé
holidays, vacation les vacances
oṣù month le mois
ìgbà season la saison
ọdún, osù méjìlá year l'an, l'année
ọjó ìbí
àjọ̀dún, àyájọ́
birthday
anniversary
l'anniversaire
ọjọ́ ìbí Krístì Christmas, (Xmas) le/la Noël
ọjọ́ àjínde Krístì,
àgbènde
Easter Pâques
ẹbùn, ọrẹ gift, (present) le cadeau
calendar le calendrier
ọdún mẹ́wàá, mẹ́wàá decade la décennie
ọgọ́run ọdún century le siècle


Yoruba English français
níwájú before avant
tẹ̀lé, lẹ́hìn after après
ìgbà ìsisìyí, wàyí now maintenant
bẹkọ láí never jamais
nígbà kan, nígbà míràn sometimes parfois
nígbà kúgbà often souvent
nígbà gbogbo, títí lái always toujours