iye - number - chiffre, nombre

Yoruba English français
1 ení, ọ̀kan, oókàn one un
2 èjì, eéjì two deux
3 ẹ̀ta, ẹẹ́ta three trois
4 ẹ̀rin, ẹẹ́rin four quatre
5 àrún, aárùn five cinq
6 ẹ̀fà, ẹẹ́fà six "
7 èje, eéje seven sept
8 ẹ̀jọ, ẹẹ́jọ eight huit
9 ẹ̀sán, ẹẹ́sàn nine neuf
10 ẹ̀wá, ẹẹ́wàá ten dix

Yoruba
11 ọ̀kanlá, oókànlá
12 èjìlá, eéjìlá
13 ẹ̀talá, ẹẹ́talá
14 ẹ̀rinlá, ẹẹ́rìnlá
15 ẹ́ẹdógún
16 ẹẹ́rìndílógún
17 eétàdílógún
18 eéjìdílógún
19 oókàndílógún
Yoruba
20 ogún, okòó
30 ọgbọ̀n
40 ogójì -> ojì
50 àádọ́ta
60 ọgọ́ta
70 àádọ́rin
80 ọgọ́rin
90 àádọ́rùn


Yoruba English français
100 ọgọ́rùn hundred cent
1 000 ẹgbẹ̀rún thousand mille
1 000
000
ẹgbẹ̀ẹgbẹ̀rún,
àádọ́ta ọkẹ́
million "
ordinal numbers - nombres ordinaux

Yoruba English français
1o èkíní níṣàjú first premier
2o èjìèkejì second deuxième
3o ẹkẹtakẹta third troisième
èkejì next prochain, suivant
ìkẹhìn, ìgbẹhìn,
ti ìkẹhìn, ní ìgbẹhìn
last dernier


les fractions

Yoruba English français
1/2 ìdajìàbọ, àbọìdáméjì half demi, la moitié
1/4 ìdámẹrin ohunkóhun quarter quart
% ìpín lọnà ọgọrun percent pourcent, le pourcentage
ẹrọ ìṣirò calculator la calculatrice