ẹdá, ẹdá ohunkóhun - la nature

Yoruba English français
ilẹ, erùpẹ earth, ground, soil la terre, le sol
amọ clay l'argile
ẹrẹ, pẹtẹpẹtẹ mud la boue
eruku, ìyẹpẹ dust la poussière
koríko grass l'herbe
koríko gbígbẹ hay le foin
igi àgbàdokoríko gbígbẹ straw la paille
gbòngbòìpilẹẹ root la racine
ewé leaf la feuille
ìtànná ewéko òdòdó flower la fleur
òdòdó olóòrùn dídùn la rose
igbóẹgàn forest la forêt
igi tree l'arbre
orúkọ igi kan pine tree le pin
igi igbó wood le bois
èédú igi charcoal le charbon de bois
panápaná firefighter, fireman le pompier
iná fire le feu
èéfí smoke la fumée
eérú ash la cendre
òkè oníná arú
èéfínìrúkè òkè gígá
volcano le volcan
òkè gíga mountain la montagne
òkè kékeré hill la colline
ihò nísàlẹ ilẹ,
ihò nínú àpátaihò inú ilẹ
cave la grotte, la caverne
àfonífojì, àfo ilẹ,
àárín òkè méjì
valley la vallée
ṣíṣe ọnà omi,
dídarí omi ṣíṣàn
dam le barrage
ọṣọrọ òjò, ìtàkìtì omi waterfall la chute d'eau, cascade
adágún lake le lac
omi ìkúdú,
àbàtà, ọgọdọ
pond l'étang
ẹrẹìrà pẹtẹpẹtẹ ẹrọfọ,
ìrà, ẹrọfọ, ẹrẹ, àbàtà
marsh le marais, marécage
plain la plaine
pápá oko tútù meadow, grassland la prairie, le pré
pápá, oko tútù,
koríko, ìjẹ ẹran
pasture le pâturage
gbagede ẹrẹìgbẹ pápá field le champ
ẹrọ àfafẹfẹ yí
windmill le moulin à vent
kọngaorísun omi water well le puits
afárá bridge le pont
odò river la rivière, le fleuve
òkun nlàagbami òkun ocean l'océan
òkun omi-iyọ sea la mer
koríko etí òkun seaweed l'algue, (le varech)
ìrúmiìgbì omiìbilù-omi sea wave la vague
oru, oruìkúku steam, vapor la vapeur
erékúsù island l'île
etí òkunẹbá òkun beach la plage
aginjùaṣálẹ desert le désert
ebè oníyanrìn þlá la dune
iyanrìn, yanrìn,
iyẹpẹ
sand le sable
òkúta wẹrẹ pebble le galet
òkúta stone la pierre
àpátaòkútañlá rock la roche, le rocher
òkúta dídán marble le marbre
òkúta oníyebíye jùlọ diamond le diamant
òkúta iyebíye pupa ruby le rubis
òkúta pupa oníyebíye sapphire le saphir
ẹ̀yà òkúta iyebíye kan amber l'ambre
ẹyìn ináèédú coal le charbon
epoòróróọrá oil, (petroleum) le pétrole
isó, afẹfẹ inú gas le gaz
onírúurú irinidẹòjéfàdákàwúrà metal le métal
òjé lead le plomb
tánganran tin l'étain
irin iron, (steel) le fer, (l'acier)
bàbàowó kọbọàkàngbà copper le cuivre
fàdákà silver l'argent
wúràìwóòrògóòlù gold l'or