àwọn oṣù
months - les mois

Yoruba English français
òkúdù June juin
agẹmọ July juillet
ògún August août
ọ̀wẹwẹ̀ September septembre
ọ̀wàrà October octobre
bélú November novembre
ọpẹ́ December décembre
ṣẹ́rẹ́ January janvier
èréle February février
ẹrẹ́nà March mars
igbe April avril
ẹ̀bíbí May mai
àwọn ìgbà
seasons - les saisons

Yoruba English français
afẹrẹ Spring le printemps
ìgbà ooru Summer l'été
ìgbà ọyẹ Autumn, (Fall) l'automne
ìgbà òtútù Winter l'hiver