èso ọmọ - le fruit

Yoruba English français
èso òro òyìnbó apple la pomme
irú èso kan pear la poire
èso kan bí ìyeyè plum la prune
irú èso kan peach la pêche
irú èso òyìnbó kan apricot l'abricot
ọsán, òrombó l'orange
òrombó nlá grapefruit le pamplemousse
ọsan wẹwẹ, òrombó kíkan lemon le citron
èso ìtakùnbàrà le melon
èso bàrà watermelon la pastèque
irú èso dídùn kan strawberry la fraise
ẹyà àgbáyun kan raspberry la framboise
ẹyà àgbáyun dúdú kan blackberry la mûre
ẹyà èso òyìnbó aláwọ dúdú kan blueberry, bilberry la myrtille
irú èso kan gooseberry la groseille à maquereau
irú èso òyìnbó kan cherry la cerise
èso àjàrà grape(s) le raisin
(èso) ọ̀pọ̀tọ́ fig la figue
èso ọpẹ dídùn date la datte
irú èkùrọ òyìnbó kan almond l'amande
àwùsá òyìnbó,
kóró éso igièkùrọẹpà
walnut, nut la noix
ẹpà peanuts les cacahuètes
àgbọn coconut la noix de coco
ọ̀pẹ òyìnbó pineapple l'ananas
ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹ́wẹ́ banana la banane
mango la mangue