ìdílé, ẹbí, ìbátan, ará
family - la famille

Yoruba English français
bàbá bàbá ẹni
bàbá ìyá ẹni
paternal grandfather
maternal grandfather
le grand-père paternel
le grand-père maternel
ìyá bàbá ẹni
ìyá ìyá ẹni
paternal grandmother
maternal grandmother
la grand-mère paternelle
la grand-mère maternelle
bàbá father, dad le père, papa
ìyá mother, mom la mère, maman
òbí le parent
ènìyàn human being l'être humain
ọkùnrin àgbà man l'homme
obìnrin woman la femme
ọkọ husband l'époux, le mari
ìyàwó, aya wife, spouse l'épouse
uncle l'oncle
ègbọ́n lobìnrin aunt la tante
ọmọkùnrin boy, son le garçon, le fils
ọmọbìnrin girl, daughter la fille
arákùnrin brother le frère
arábìnrin sister la sœur
ìbejì, èjìrẹ́ twin le jumeau
ọmọ, ọmọdé, èwe child l'enfant
ọmọ ọwọ́, ọmọ jòjòló baby le bébé
àlejò guest l'invité
ọ̀rẹ́, ẹnìkejì friend l'ami
ọ̀tá, oníkeéta enemy l'ennemi
aládúgbò neighbour le voisin