àwọ̀ - color - la couleur

  Yoruba English français
  àwọ̀ igi, àwọ̀ ara brown marron
  dúdú black noir
  àwọ̀ eléérú grey, gray gris
  funfun white blanc
  pupa rúsúrúsú yellow jaune
  àwọ̀ òféfèé orange "
  pupa red rouge
  pupa fẹẹrẹ pink rose
  àwọ̀ elésè àlùkò,
àwọ̀ àlùkò, elésè àlùkò
purple violet
  àwọ̀ ojú ọ̀run,
àwọ̀ sánmà
blue bleu
  àwọ̀ ewé green vert