ara, (ẹgbẹ́) - body - le corps

Yoruba English français
ara skin la peau
irun ara
irun orí
hair les poils
les cheveux
orí head la tête
iwájú orí forehead le front
egungun agbárí skull le crâne
ọpọlọ, ọgbọ́n, òye brain le cerveau
ojú, (iwájú) face le visage
ojú eye l'œil
irun ìpénpéjú eyelash le cil
bèbè ojú eyebrow le sourcil
ìpénpéjú eyelid la paupière
ẹyin ojú eyeball le globe oculaire
etí, ṣirì-ọkà ear l'oreille
imú nose le nez
ihò imú nostril la narine
irun imu ọkùnrin mustache la moustache
irùngbọ̀n beard la barbe
ẹrẹkẹ cheek la joue
ète lip la lèvre
ẹnu mouth la bouche
ahọ́n tongue la langue
ehín tooth la dent
egungun párí ẹkẹ jaw la mâchoire
ìgbọn, àgbọ̀n chin le menton
ọrùn, ẹ̀mí neck le cou
ọfun, ọ̀nà ọfun throat la gorge
àyà, ìgẹ chest la poitrine
ọmú, ọyọ̀n breast les seins
orí ọmú nipple, teat le téton
ọkàn heart le cœur
ẹ̀jẹ blood le sang
ẹdọ fóóró, ọdẹfóró lung le poumon
ìwọ́, ìdodo navel le nombril
inú, ikùn belly, stomach le ventre, l'estomac
ìfun inúìwọrọkù intestine l'intestin
ẹ̀dọ liver le foie
iwe, ọlọ-inú kidney le rein
agbára ọgbọ́n nerve le nerf
isan le muscle
egungun bone l'os
egungun ara skeleton le squelette
egungun ẹ̀hìn, (ògóòró) back, backbone le dos
egungun ihà/àyà rib la côte
èjìká shoulder l'épaule
apá arm le bras
abíyá armpit l'aisselle
ìgbọnwọ, ìgúnpá elbow le coude
ọrùn ọwọ́ wrist le poignet
ìkuùkù fist le poing
ọwọ́ hand la main
àtànpàkò thumb le pouce
ìka ọwọ́ finger le doigt
èékánná ìka ọwọ́ fingernail, nail l'ongle
okó penis le pénis, (la verge)
òbò vagina le vagin
àmùṣu, ihò-ìdí l'anus
ìdí buttock la fesse
itan thigh la cuisse
ẹsẹ̀ leg la jambe
orúkún, ekún knee le genou
egungun orúkún/ekún kneecap, (patella) la rotule
iṣu ẹsẹ̀ calf le mollet
kókósè, ọrùn-ẹsẹ̀ ankle la cheville
gìgísẹ̀ heel le talon
ẹsẹ̀ foot le pied
ọmọ ìka ẹsẹ̀ toe l'orteil
ìlera, dídá ara - health - la santé

Yoruba English français
nílera, tagun healthy en bonne santé
alarùn, alaisàn ill, sick malade
àrùn, àìsàn disease la maladie
ọkọ̀ aláìsàn l'ambulance
ilé ìwòsàn hospital l'hôpital
ilé ìtọ́jú oríṣiríṣí ààrùn clinic la clinique
olùtọ́, alágbàtọ́,
ọlójọ̀jọ̀ ọmọ
nurse l'infirmière
onísègùn,
olóyè nínú orísìíríìsí ẹ̀kọ́
physician, medical doctor le médecin, "docteur"
oníṣègùn eyín dentist le dentiste
onísègùn alábẹ surgeon le chirurgien
ilé elégbògi
elégbògi apo-egbògi
pharmacy, drugstore
pharmacist
la pharmacie
le pharmacien
egbògi, ògùn medication le médicament