ojú ọjọ́/ọ̀run - weather
afẹ́fẹ́ ilẹ̀, àkókòìgbà - climate - le climat

Yoruba English français
ilẹ̀, ayé, erùpẹ̀ Earth la Terre
òṣùpá oṣù moon la lune
ìràwọ̀ star l'étoile
òrùn sun le soleil
ríran òrùn sunshine, light la lumière
òjìji, ìbòji shadow, shade l'ombre
ọ̀run, ojú ọ̀run sky le ciel
ìkúùkùàwọ-sánmàojú
ọrunojú-sánmà
cloud le nuage
ìkùúkùù, (kùrukùru) fog, mist le brouillard, la brume
afẹ́fẹ́, òfúrufú,
ojú sánmọ̀
l'air
afẹ́fẹ́, ẹ̀fúfú wind le vent
ìjì, ẹfúfu líle storm la tempête
àrá thunder le tonnerre
ìkọ sàn, ìmọ́lẹ̀ flash, lightning l'éclair
òṣùmàrè rainbow l'arc-en-ciel
òjò rain
raindrop
la pluie
la goutte de pluie
agbòjò
agbòrùn
umbrella
 
le parapluie
le parasol
òtútù níní frost le gel
yìnyín, (omi dídì) ice la glace


Yoruba English français
gbígbóná, (gbóná diẹ)
ìgbóná
hot, warm
heat
chaud
la chaleur
tútù
òtútù
cold
the cold
froid
le froid
gbẹ, gbẹrẹfu, gbígbẹ,
(láìlómi)
dry sec
rin, tutù
orinrin, itutù
humid, (wet)
humidity
humide
l'humidité